Names – Orúkọ
Orúkọ Ọkùnrin (Male Names)
- Adéyẹmọ (A crown befits the child)
- Kọ́ládé (Bring honor home)
- Káyọ̀dé (Bring joy in)
- Olúwọlé (The Lord enters the house)
- Olúṣẹ́gun (The Lord won the battle)
- Ayọ̀dèjì (Joy becomes two)
- Ọbáfẹ́mi (The king loves me)
- Olúsànyà (God compensates for suffering)
- Akínbíyìí (A valiant man gave birth to this one)
- Adélékè (The crown triumphs)
- Babátúndé (Father comes back)
Orúkọ Obìnrin (Female Names)
Orúkọ Ọkùnrin tàbí Obìnrin (Male or Female Names)